Awon ibeere isale yii dale asa ile Yoruba, awon idahun to ye ti farahan gbangba.
Ewo lo je mo ise agbede
(a) ebiti
(b) apasa
(d) kannakanna
(e) ewiri
Sango ni a n ki ni
(a) lakaaye, osinmole
(b) eni soji, to semu
(d) ogiri oko
(e) oloju orogbo
Ogidi-olu ni a n ki omo to
(a) ni ika owo mefa
(b) mese waye
(d) doju dele nigba ti a bi i
(e) wa ninu apo nigba ti a bi i
Ninu asa ibile Yoruba, ki ni a koko fi n ki alejo kaabo
(a) owo
(b) omi
(d) obi
(e) ounje
Eree ni a fi n se
(a) akara
(b) eko
(d) ojojo
(e) aadun
Awon wo ni won n lo “edan”
(a) olosun
(b) ologbooni
(d) olobatala
(e) oloro
Ila ti awon omo alaafin maa n ko ni
(a) pele
(b) keke
(d) abaja
(e) gonbo
Ki ni itumo “ogbo n run”
(a) ogberi wa ni itosi
(b)alagbara ba afefe je
(d) Egbin kan wa ni itosi
Ibi ti a ti n se adi ni a n pe ni
(a) aro
(b) ebu
(d) bawo
(e) iba
Obinrin ti oko feran ju ni a n pe ni
(a) orogun
(b) olori
(d) iyawo
(e) aayo
Orisa wo lo maa n gba igbin
(a) obatala
(b) sango
(d) esu
(e) sanponna
____ ni a n ki pe e ku owo lomi
(a) akoseyege
(b) onisiile
(d) omolokuu
(e) abiyamo
Ajigbese gbowo gungi tumo si pe o
(a) gbagbe
(b) sa pamo
(d) lo sode
(e) ku
Ewo ni ajokoose
(a) ekun meran
(b) bojuboju
(d) eye meloo
(e) ayo
A kii jokoo seti odo je mo eko
(a) imototo
(b) ifarabale
(d) ibowofagba
(e) imowon-ara-eni
Oku ejo loba i da je mo asa
(a) isile
(b) isigun
(d) isupo
(e) iselu
Esentaye jemo asa
(a) ogun jija
(b) iranra-eni-lowo
(d) omo bibi
(e) ikoseyege
Ewo ni oruko amutorunwa
(a) ayanwale
(b) ige
(d) oparinde
(e) abimbola
Idile wo lo n so omo ni opadiji
(a) onisango
(b) olorisa-oko
(d) olasanyin
(e) eleegun
______ ni a n pe akobi omo to je obinrin ni ile Yoruba
(a) dalemosu
(b) beere
(d) aremo
(e) omoloju
Irinse fun aso hihun ni
(a) keke
(b) owu
(d) iwana
(e) awon
Irufe ila wo ni Ondo n ko
(a) keke
(b) abaja
(d) pele
(e) gonbo
Ki ni aso ogun
(a) beere
(b) mariwo
(d) gbodogi
(e) eweeran
Ohun elo ogun jija ni
(a) oso
(b) eya
(d) ibon
(e) emu
CLICK HERE FOR MORE >>>>